Posts

Showing posts from October, 2013

Ope mi koyito o!

Image
I decided to do this post in my native tongue! Caveat- I am actually not as fluent in it as I would like but here goes. There are no accents as I do not have a Yoruba keyboard but I do hope you can make some sense of it all. Modupe fun 1. Awon ore mi ti olorun fun mi. Akoko ninu won ni ikeji mi Oluwatoyin! Modupe lowo olorun to fun mi lore lati orun wa. Ore to fe mi gan, to mo si fe gan. Oluwatoyin je enikan ti o momi dele, to si ma sooto fun mi ni gbogbo igba. 2. Modupe fun awon ore iyoku ti moni, adura mi nipe ki Olorun fun yin ni gbogbo nkan ti e ban bere lowo oluwa fun. 3. Orin Ayo ati Orin ti a man fi sin oluwa. Leni mo joko gbo Orin Sinachi 'Mo me eni ti mo je'. Ayokun lokan mi ni igbati mo bere si korin ati bere si ma jo niwaju oluwa. O da ka yin oluwa logo ni gbogbo igba! 4. Awon obi mi ati awon ebi mi. Mo ba won soro lori ero abanisoro lose to koja, inu midun nitoripe ayo ni gbogbo won wa. 5. Ileri mi bi omo olorun. Ojo kan bo ti gbogbo wa ma duro ni iwa