Ope mi koyito o!
I decided to do this post in my native tongue! Caveat- I am actually not as fluent in it as I would like but here goes. There are no accents as I do not have a Yoruba keyboard but I do hope you can make some sense of it all.
Modupe fun
1. Awon ore mi ti olorun fun mi. Akoko ninu won ni ikeji mi Oluwatoyin! Modupe lowo olorun to fun mi lore lati orun wa. Ore to fe mi gan, to mo si fe gan. Oluwatoyin je enikan ti o momi dele, to si ma sooto fun mi ni gbogbo igba.
2. Modupe fun awon ore iyoku ti moni, adura mi nipe ki Olorun fun yin ni gbogbo nkan ti e ban bere lowo oluwa fun.
3. Orin Ayo ati Orin ti a man fi sin oluwa. Leni mo joko gbo Orin Sinachi 'Mo me eni ti mo je'. Ayokun lokan mi ni igbati mo bere si korin ati bere si ma jo niwaju oluwa. O da ka yin oluwa logo ni gbogbo igba!
4. Awon obi mi ati awon ebi mi. Mo ba won soro lori ero abanisoro lose to koja, inu midun nitoripe ayo ni gbogbo won wa.
5. Ileri mi bi omo olorun. Ojo kan bo ti gbogbo wa ma duro ni iwaju ite olorun. Emi ni ileri pe ojo ayo lo ma je fun mi. Iwo n ko? Olorun fe ki gbogbo wa mo won bi bibeli se so! Ka kepe oluwa, ka si gbagbo ninu okan wa pe Jesu lomo olorun, o de wa saiye wa ku fun gbogbo wa lori igi agbelebu. Jesu loluwa mi! Iwo n kan? Se o ti gba Jesu saiye re? Ola le pe ju o! Ma je ko pe mo.
6. Bibeli. Ni tooto bibeli je Iwe aiye. O ye ka ma ka ni gbogbo igba o!
7. Ounje, Omi mimu, Orun, Ojo, Afefe, ati bebelo.
8. Awon alufa ijo ati ijo olorun to ma n fun wa ni oro iye.
9. Awon Olori Ijo to n so otito ti olorun fun won, ti won de fi oro wan paamo ninu eleyi ti olorun fun won lati so.
10. Aiye. Modupe pe mo wa laiye mo de si wa laiye!

Comments
Post a Comment