Irohin latodo mi! (News from me)
The inspiration for this post came from reading this blog http://irinajoyinbo.wordpress.com My apologies to non-Yoruba speakers but you will need to be able to read yoruba or find an interpreter to understand the post below:) I have also put up pictures and a video so you have a pretty good idea of the topics of my rants:)! O ti pe ti mo ti fe ko awon oro yii sile sugbon mi o ti setan lati se afi lehin ti mo ka 'blog' Kayode, mo ranti pe mo le ko awon oro yii ni ede ti die laarin awon to ma n ka 'blog' mi le ka. Kii sepe mo ni nkan fipamo sugbon lasiko, awon oro kan wa to dun so lede mi, ko de si oro ninu ede geesi to le mu oyin kuro ninu okuta. Nkan sele leni ti o ya mi lenu gan.....................................................................................................................................................................hmmm e ma binu iya to ya mi o je n ko le:) Awon ile ologe ni awon oro mi to ku wa fun 1. Ki ni idi ti awon okunrin loni ma n wo sok...