Picture post in Yoruba!

Mo koko fe bere aforiji lowo awon omo yoruba fun akikole mi ni yoruba. Mo mope yoruba mi o da rara, paapaa julo mi o fi ami sori awon oro mi. Mo mope nigba min awon oro mi ma mu n yin binu nitoripe mi o ko daadaa. Sugbon mo fe gbiyanju si, o de fun mi ni ayo kekere ti m ba ti ko iwe mi ni yoruba. E dariji mi o!

Kini mo fe kole leni. Opolopo oro wa. Sugbon mo fe fi han yin awon foto die laarin eyi ti mo ya nigbati mo n rin kakiri ilu die. Irinajo mi po sugbon mogbagbe lati tun batiri camera mi she, ko je ki n ya foto pupo! E gbadun awon foto die ti mo ya.

Irun sisi kekere kan!:)

Ko da to bi mo seri! Camera mi o mu ewa ile yi jade rara.


Loju titi kan ni Detroit awon 'artists' fi bata se 'art work'! Iyalenu mi nipe won lo bata titun won de kun won pelu painti!


Bata yi o jo tutun sha!


E sha momi, ounje o n pe kuro loju camera mi. Mo lo si Dearborn lodun to koja, igbati mo de de Detroit lodun yi, mi o gbagbe 'shatila'. Mo mu awon eyan mi de be na! Ounje won dun gididani o!

Ounje Shatila-Baclava orisirisi! Ijekuje po:)


Opolopo ile to wa ni Detroit, jo ile yi. Window ti fo, ina ti jo pupo lara won! O je nkan to ba ile yi je, k ise kekere.


Awon foto ti mo ya lana! Won o po rara!:(



Science Museum ni Detroit!

Ile yi wa ni Windsor! Osa kan je ila Detroit ati Windsor. A lo si egbe omi lati lo wo!

Awon foto to ku mo ya ni Detroit.




Comments

  1. This is a beautiful post. I wonder where the comments are.

    I've done brief sentences in Yoruba but my fluency is limited. One day, one day!

    ReplyDelete
  2. Thanks NakedSha Im sure those who understand the language are cringing on my behalf:) Thanks for stopping by and following! Little drops definitely make a mighty ocean!

    ReplyDelete

Post a Comment

Popular posts from this blog

Death III

Death 5

My Mother Tongue!